1. Kor 13:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi mo si nfi gbogbo ohun ini mi bọ́ awọn talaka, bi mo si fi ara mi funni lati sun, ti emi kò si ni ifẹ, kò li ere kan fun mi.

1. Kor 13

1. Kor 13:1-8