1. Kor 12:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi ẹ̀ya kan ba si njìya, gbogbo ẹ̀ya a si jùmọ ba a jìya; tabi bi a ba mbọla fun ẹ̀ya kan, gbogbo ẹ̀ya a jùmọ ba a yọ̀.

1. Kor 12

1. Kor 12:22-31