1. Kor 12:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oju kò si le wi fun ọwọ́ pe, emi kò ni ifi ọ ṣe: tabi ki ori wi ẹ̀wẹ fun ẹsẹ pe, emi kò ni ifi nyin ṣe.

1. Kor 12

1. Kor 12:19-24