1. Kor 10:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ti gbogbo wọn si mu ohun mimu ẹmí kanna: nitoripe nwọn nmu ninu Apata ẹmí ti ntọ̀ wọn lẹhin: Kristi si li Apata na.

1. Kor 10

1. Kor 10:1-12