1. Joh 4:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nipa eyi li a gbé fi ifẹ Ọlọrun hàn ninu wa, nitoriti Ọlọrun rán Ọmọ bíbi rẹ̀ nikanṣoṣo si aiye, ki awa ki o le yè nipasẹ rẹ̀.

1. Joh 4

1. Joh 4:6-13