1. Joh 4:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Olufẹ, ẹ jẹ ki a fẹràn ara wa: nitori ifẹ ti ọdọ Ọlọrun wá; ati gbogbo ẹniti o ba ni ifẹ, a bí i nipa ti Ọlọrun, o si mọ̀ Ọlọrun.

1. Joh 4

1. Joh 4:4-15