1. Joh 3:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ohunkohun ti awa ba bère, awa nri gbà lọdọ rẹ̀, nitoriti awa npa ofin rẹ̀ mọ́, awa si nṣe nkan wọnni ti o dara loju rẹ̀.

1. Joh 3

1. Joh 3:20-24