1. Joh 2:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Aiye si nkọja lọ, ati ifẹkufẹ rẹ̀: ṣugbọn ẹniti o ba nṣe ifẹ Ọlọrun ni yio duro lailai.

1. Joh 2

1. Joh 2:14-23