1. A. Ọba 9:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE) O si ṣe, bi Solomoni ti pari kikọ́ ile Oluwa, ati ile ọba, ati gbogbo ifẹ Solomoni ti o wù u lati ṣe,