1. A. Ọba 8:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kò si nkankan ninu apoti-ẹri bikoṣe tabili okuta meji, ti Mose ti fi si ibẹ ni Horebu nigbati Oluwa ba awọn ọmọ Israeli dá majẹmu, nigbati nwọn ti ilẹ Egipti jade.

1. A. Ọba 8

1. A. Ọba 8:1-11