1. A. Ọba 8:53 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti iwọ ti yà wọn kuro ninu gbogbo orilẹ-ède aiye, lati mã jẹ ini rẹ, bi iwọ ti sọ lati ọwọ Mose iranṣẹ rẹ, nigbati iwọ mu awọn baba wa ti Egipti jade wá, Oluwa Ọlọrun.

1. A. Ọba 8

1. A. Ọba 8:43-56