1. A. Ọba 8:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn alufa kò si le duro ṣiṣẹ nitori awọsanma na: nitori ogo Oluwa kún ile Oluwa.

1. A. Ọba 8

1. A. Ọba 8:4-15