1. A. Ọba 6:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ọ̀dẹdẹ niwaju tempili ile na, ogún igbọnwọ ni gigùn rẹ̀, gẹgẹ bi ibú ile na: igbọnwọ mẹwa si ni ibú rẹ̀ niwaju ile na.

1. A. Ọba 6

1. A. Ọba 6:1-12