1. A. Ọba 6:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si fi awọn kerubu sinu ile ti inu lọhun, nwọn si nà iyẹ-apa kerubu na, tobẹ̃ ti iyẹ-apa ọkan si kàn ogiri kan, ati iyẹ-apa kerubu keji si kàn ogiri keji: iyẹ-apa wọn si kàn ara wọn larin ile na.

1. A. Ọba 6

1. A. Ọba 6:21-28