1. A. Ọba 6:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Solomoni si fi wura ailadàlu bò ile na ninu: o si fi ẹwọ́n wura ṣe oju ibi-mimọ́-julọ, o si fi wura bò o.

1. A. Ọba 6

1. A. Ọba 6:12-22