1. A. Ọba 6:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si kọ́ ogún igbọnwọ ni ikangun ile na, lati ilẹ de àja ile na li o fi apako kedari kọ́, o tilẹ kọ́ eyi fun u ninu, fun ibi-idahùn, ani ibi-mimọ́-julọ.

1. A. Ọba 6

1. A. Ọba 6:12-18