1. A. Ọba 4:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Solomoni si ni ijoye mejila lori gbogbo Israeli, ti o npèse onjẹ fun ọba ati agbo-ile rẹ̀; olukuluku li oṣu tirẹ̀ li ọdun ni npese.

1. A. Ọba 4

1. A. Ọba 4:1-16