1. A. Ọba 3:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si dide li ọ̀ganjọ, o si gbe ọmọ mi lati iha mi, nigbati iranṣẹ-birin rẹ sun, o si tẹ́ ẹ si aiya rẹ̀, o si tẹ́ okú ọmọ tirẹ̀ si aiya mi.

1. A. Ọba 3

1. A. Ọba 3:15-26