1. A. Ọba 3:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọkan ninu wọn si wipe, Jọwọ, oluwa mi, emi ati obinrin yi ngbe ile kan; emi si bi ọmọ ni ile pẹlu rẹ̀.

1. A. Ọba 3

1. A. Ọba 3:14-18