1. A. Ọba 3:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

SOLOMONI si ba Farao ọba Egipti da ana, o si gbe ọmọbinrin Farao ni iyawo, o si mu u wá si ilu Dafidi, titi o fi pari iṣẹ ile rẹ̀, ati ile Oluwa, ati odi Jerusalemu yika.

1. A. Ọba 3

1. A. Ọba 3:1-5