1. A. Ọba 22:50 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jehoṣafati si sùn pẹlu awọn baba rẹ̀, a si sin i pẹlu awọn baba rẹ̀ ni ilu Dafidi, baba rẹ̀: Jehoramu, ọmọ rẹ̀, si jọba ni ipò rẹ̀.

1. A. Ọba 22

1. A. Ọba 22:46-52