1. A. Ọba 22:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba Israeli ati Jehoṣafati, ọba Juda joko olukulùku lori itẹ́ rẹ̀, nwọn wọ̀ aṣọ igunwa wọn ni ita ẹnu-bode Samaria, gbogbo awọn woli na si nsọtẹlẹ niwaju wọn.

1. A. Ọba 22

1. A. Ọba 22:6-16