1. A. Ọba 20:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Benhadadi si ranṣẹ si i, o si wipe, Ki awọn oriṣa ki o ṣe bẹ̃ si mi, ati jù bẹ̃ lọ pẹlu bi ẽkuru Samaria yio to fun ikunwọ fun gbogbo enia ti ntẹle mi.

1. A. Ọba 20

1. A. Ọba 20:1-14