1. A. Ọba 2:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si wipe, Ibere kekere kan li emi ni ibere lọwọ rẹ; máṣe dù mi. On si wipe, mã tọrọ, iya mi; nitoriti emi kì yio dù ọ.

1. A. Ọba 2

1. A. Ọba 2:12-24