1. A. Ọba 2:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọjọ ti Dafidi jọba lori Israeli jẹ ogoji ọdun: ni Hebroni o jọba li ọdun meje, ni Jerusalemu o si jọba li ọdun mẹtalelọgbọn.

1. A. Ọba 2

1. A. Ọba 2:4-18