1. A. Ọba 19:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Jesebeli rán onṣẹ kan si Elijah, wipe, Bẹ̃ni ki awọn òriṣa ki o ṣe si mi ati jù bẹ̃ lọ pẹlu, bi emi kò ba ṣe ẹmi rẹ dabi ọkan ninu wọn ni iwoyi ọla.

1. A. Ọba 19

1. A. Ọba 19:1-8