1. A. Ọba 18:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si pin ilẹ na lãrin ara wọn, lati là a ja: Ahabu gba ọ̀na kan lọ fun ara rẹ̀, Obadiah si gba ọ̀na miran lọ fun ara rẹ̀.

1. A. Ọba 18

1. A. Ọba 18:1-7