1. A. Ọba 18:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. O si ṣe, lẹhin ọjọ pupọ, ọ̀rọ Oluwa tọ Elijah wá lọdun kẹta, wipe, Lọ, fi ara rẹ hàn Ahabu; emi o si rọ̀ òjo sori ilẹ.

2. Elijah si lọ ifi ara rẹ̀ han Ahabu. Iyan nla si mu ni Samaria.

1. A. Ọba 18