1. A. Ọba 17:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si dide, o si lọ si Sarefati. Nigbati o si de ibode ilu na, kiyesi i, obinrin opó kan nṣa igi jọ nibẹ: o si ke si i, o si wipe, Jọ̃, bu omi diẹ fun mi wá ninu ohun-elo, ki emi ki o le mu.

1. A. Ọba 17

1. A. Ọba 17:6-15