1. A. Ọba 16:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati iyokù iṣe Baaṣa, ati ohun ti o ṣe, ati agbara rẹ̀, a kò ha kọ wọn sinu iwe ọ̀rọ ọjọ awọn ọba Israeli.

1. A. Ọba 16

1. A. Ọba 16:1-10