1. A. Ọba 16:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Omri si sùn pẹlu awọn baba rẹ̀, a si sin i ni Samaria: Ahabu ọmọ rẹ̀ si jọba ni ipò rẹ̀.

1. A. Ọba 16

1. A. Ọba 16:24-30