1. A. Ọba 16:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati o bẹ̀rẹ si ijọba, bi o ti joko li ori itẹ rẹ̀, o lù gbogbo ile Baaṣa pa: kò kù ọmọde ọkunrin kan silẹ, ati awọn ibatan rẹ̀ ati awọn ọrẹ́ rẹ̀.

1. A. Ọba 16

1. A. Ọba 16:10-12