1. A. Ọba 14:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lọ, sọ fun Jeroboamu, pe, Bayi li Oluwa Ọlọrun Israeli wi, Nitori bi mo ti gbé ọ ga lati inu awọn enia, ti mo si fi ọ jẹ olori Israeli enia mi.

1. A. Ọba 14

1. A. Ọba 14:1-17