1. A. Ọba 14:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Aya Jeroboamu si ṣe bẹ̃, o si dide, o si lọ si Ṣilo, o si wá si ile Ahijah. Ṣugbọn Ahijah kò riran; nitoriti oju rẹ̀ fọ́ nitori ogbó rẹ̀.

1. A. Ọba 14

1. A. Ọba 14:1-9