1. A. Ọba 14:29-31 Yorùbá Bibeli (YCE)

29. Iyokù iṣe Rehoboamu, ati gbogbo ohun ti o ṣe, a kò ha kọ wọn sinu iwe ọ̀rọ ọjọ awọn ọba Juda?

30. Ogun si wà lãrin Rehoboamu ati Jeroboamu li ọjọ wọn gbogbo.

31. Rehoboamu si sùn pẹlu awọn baba rẹ̀, a si sin i pẹlu awọn baba rẹ̀ ni ilu Dafidi. Orukọ iya rẹ̀ si ni Naama, ara Ammoni. Abijah, ọmọ rẹ̀ si jọba ni ipò rẹ̀.

1. A. Ọba 14