1. A. Ọba 13:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun u pe, Woli li emi pẹlu gẹgẹ bi iwọ; angeli si sọ fun mi nipa ọ̀rọ Oluwa wipe, Mu u ba ọ pada sinu ile rẹ, ki o le jẹ onjẹ ki o si le mu omi. Ṣugbọn o purọ fun u.

1. A. Ọba 13

1. A. Ọba 13:17-22