1. A. Ọba 13:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Woli àgba kan si ngbe Beteli: ọmọ rẹ̀ de, o si rohin gbogbo iṣẹ ti enia Ọlọrun na ti ṣe li ọjọ na ni Beteli fun u: ọ̀rọ ti o sọ fun ọba nwọn si sọ fun baba wọn.

1. A. Ọba 13

1. A. Ọba 13:1-19