1. A. Ọba 12:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

REHOBOAMU si lọ si Ṣekemu, nitori gbogbo Israeli li o wá si Ṣekemu lati fi i jẹ ọba.

1. A. Ọba 12

1. A. Ọba 12:1-10