1. A. Ọba 10:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba si ṣe ki fadakà ki o wà ni Jerusalemu bi okuta, ati igi kedari li o ṣe ki o dabi igi sikamore ti mbẹ ni afonifoji fun ọ̀pọlọpọ.

1. A. Ọba 10

1. A. Ọba 10:18-29