1. A. Ọba 10:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ọba ni ọkọ̀ Tarṣiṣi kan pẹlu ọkọ̀ Hiramu li okun: ẹ̃kan li ọdun mẹta li ọkọ̀ Tarṣiṣi idé, ti imu wura ati fadaka, ehin-erin ati inakí ati ẹiyẹ-ologe wá.

1. A. Ọba 10

1. A. Ọba 10:12-24