1. A. Ọba 10:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe ọdunrun apata wura lilù, oṣuwọn wura mẹta li o tán si apata kan: ọba si ko wọn si ile igbo Lebanoni.

1. A. Ọba 10

1. A. Ọba 10:16-24