1. A. Ọba 1:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Baba rẹ̀ kò si bà a ninu jẹ rí, pe, Ẽṣe ti iwọ fi ṣe bayi? On si ṣe enia ti o dara gidigidi: iya rẹ̀ si bi i le Absalomu.

1. A. Ọba 1

1. A. Ọba 1:5-13