1. A. Ọba 1:53 Yorùbá Bibeli (YCE)

Solomoni ọba si ranṣẹ, nwọn mu u sọkalẹ lori pẹpẹ. On si wá, o si foribalẹ̀ fun Solomoni ọba: Solomoni si wi fun u pe, Mã lọ ile rẹ.

1. A. Ọba 1

1. A. Ọba 1:47-53