1. A. Ọba 1:51 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si wi fun Solomoni pe, Wò o, Adonijah bẹ̀ru Solomoni ọba: si kiyesi i, o di iwo pẹpẹ mu, o nwipe, Ki Solomoni ọba ki o bura fun mi loni pe, On kì yio fi idà pa iranṣẹ rẹ̀.

1. A. Ọba 1

1. A. Ọba 1:44-53