1. A. Ọba 1:45 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sadoku, alufa ati Natani, woli si ti fi ororo yàn a li ọba ni Gihoni: nwọn si fi ayọ̀ goke lati ibẹ wá, tobẹ̃ ti ilu si nho. Eyi ni ariwo ti ẹ ti gbọ́.

1. A. Ọba 1

1. A. Ọba 1:36-49