1. A. Ọba 1:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sadoku alufa si mu iwo ororo lati inu agọ, o si dà a si Solomoni lori; nwọn si fun fère; gbogbo enia si wipe, Ki Solomoni ọba ki o pẹ.

1. A. Ọba 1

1. A. Ọba 1:34-43