1. A. Ọba 1:37 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi Oluwa ti wà pẹlu oluwa mi ọba, gẹgẹ bẹ̃ni ki o wà pẹlu Solomoni, ki o si ṣe itẹ rẹ̀ ki o pọ̀ jù itẹ oluwa mi, Dafidi ọba lọ.

1. A. Ọba 1

1. A. Ọba 1:29-47