1. A. Ọba 1:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi, ọba si dahùn o si wipe, Ẹ pè Batṣeba fun mi. On si wá siwaju ọba, o si duro niwaju ọba,

1. A. Ọba 1

1. A. Ọba 1:22-38