1. A. Ọba 1:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Natani si wipe, oluwa mi, ọba! iwọ ha wipe, Adonijah ni yio jọba lẹhin mi ati pe, on o si joko lori itẹ mi bi?

1. A. Ọba 1

1. A. Ọba 1:16-33