1. A. Ọba 1:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina, wá nisisiyi, emi bẹ̀ ọ, emi o si fun ọ ni ìmọ, ki iwọ ki o le gbà ẹmi rẹ là, ati ẹmi Solomoni ọmọ rẹ.

1. A. Ọba 1

1. A. Ọba 1:11-17